Gloria Foriwa
Gloria Adwoa Foriwa jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 11, óṣu May ni ọdun 1981. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbọrin ghatel gẹgẹbi forward[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Gloria Adwoa Foriwa<r | ||
Ọjọ́ ìbí | 11 Oṣù Kàrún 1981 | ||
Playing position | Forward (association football) | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Ghatel Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | 6 | (1) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Gloria kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 2007[2].