Gloria Oloruntobi
Gloria Oloruntobi (tí wọ́n bí ní Oṣù kejì ọjọ́ kẹfà, ọdún 1997), tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Maraji, jẹ́ Òṣèré Apanilẹ́rìn-ín Nàìjíríà.[1][2][3][4] Ó bẹ̀rẹ̀ ìgbẹ́sí ayé rẹ̀ pẹ̀lú vídíò lip sync àti kọ orin olórin .[5] Maraji ṣeré nínu àwọn vídíò apanilẹ́rìn-ín kékeré àti lo àwọn ẹ̀ka-èdè àti ohùn oríṣiríṣi láti bá àwọn ẹ̀dá tó kópa lọ.[6][7]
Gloria Oloruntobi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kejì 1997 |
Orúkọ míràn | Maraji |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Yunifásitì Covenant |
Iṣẹ́ | Content creator, comedienne, skit maker |
Ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeMaraji jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Ẹdó. Ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ pẹ̀lú ẹ̀kọ́ ibáṣepọ̀ láàárín àwọn ìlú (international relations) láti Fáṣítì Covenant ní ọdún 2017.[8][9]
Maraji wà ní vídíò orin Falz's "Something Light" àti Yemi Alade's "Single and Searching" ".[10][11]
Àwọn oyè tó gbà àti àwọn ibi tí wọ́n pẹ̀ ẹ́ sí
àtúnṣeWọ́n pé Maraji fún Oyè eré apanilẹ́rìn-ín ni ọdún 2017 àti ọdún 2018 tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ The Future Awards Africa.[12][13][14] Wọ́n pẹ̀ ẹ́ fún Eré Apanilẹ́rìn-ín ní ọdún 2018 fún City People Music Awards.[15]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Meet the Nigerian creative who turned social media to her audience". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-13. Archived from the original on 2020-02-11. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ Nwosu, I. K. (2018-09-11). "Get to Know Comedian/Content Creator Gloria Oloruntobi (Maraji) on #The25Series". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "Maraji Says She Collects An Average Of N500,000 Per Skit And Nigerians Are Not Having It". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-09. Archived from the original on 2018-10-11. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "YNaija presents: The 100 most influential Nigerians In Film in 2019 » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-11-01. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "The Future Awards Africa Prize for Comedy". The Future Awards Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-02. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "Top 10 people social media blew up". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-12-08. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "Celebrities who became famous through Instagram - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "The Business Of 60 Second Skits: How Your Favourite Comedians Are Cashing Out On Instagram". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-16. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "See Who Made Top 25 Under-30 Nigerian Superstars - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ Reporter (2018-10-06). "20 Top Instagram Comedians Making Waves Online". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "10 Nigerian comedians who became popular on Instagram - P.M. News". www.pmnewsnigeria.com. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "#NigeriasNewTribe: The Future Awards Africa unveils nominees for 2017 edition". The Future Awards Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-11-24. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "Burna Boy, Adesua Etomi, Maraji, others make 2018 The Future Awards nominee list". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-03. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "The Future Awards Africa 2018 Nominees List". guardian.ng. Archived from the original on 2018-12-27. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ Pomaa, Precious (2019-03-19). "Meet 10 Guys Who Made Their 1st Million From INSTAGRAM". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-30.