Gloria Young
Gloria Young (bí ní ọjọ́ kẹrin oṣù kejì ọdún 1967[1][2]) jẹ́ òṣèré [3][4][5][6][7]ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó gbà àmì ẹ̀yẹ Movie Couple of the Year láti ọ̀dọ̀ City People Entertainment Awards ní ọdún 2018.[8]
Gloria Young | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Gloria Anozie-Young 4 Oṣù Kejì 1967 Abia State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé Àti Ẹ̀kọ́ Rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Gloria sí ìpínlẹ̀ Abia.[9] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Methodist Girls High School ní Yaba ní ìpínlẹ̀ Èkó. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ni orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.[10][11]
Iṣẹ́
àtúnṣeGloria bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi oníróyìn.[12] Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré ní ọdún 2014 lẹ́hìn tí ó kó ipa Doris nínú eré Glamour Girls.[13]
Àmì Ẹ̀yẹ
àtúnṣeYear | Award | Category | Result | Àdàkọ:Refh |
---|---|---|---|---|
2018 | City People Entertainment Awards | Movie Couple of the Year | Gbàá | [8] |
2021 | Africa Movie Academy Awards | Best Actress in a Supporting Role | Wọ́n pèé | [14] |
Ayé Ti Rẹ̀
àtúnṣeYoung ti ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ẹlẹ́gbẹ́ Nollywood rẹ̀ Norbert Young àti pé àwọn méjéèjì ní ọmọ mẹ́ta papọ̀. .[15] Ìdíje eré bọ́ọ̀lù tuntun kan ni wọ́n ṣètò ní pápá ìṣeré ti orílẹ̀-èdè ní Surulere, ìpínlẹ̀ Èkó ní òmìrán láti ṣe ayẹyẹ 'jubilee' fàdákà rẹ̀ ní Nollywood. [16][17][18]
Àṣàyàn Àwọn Eré Tí Ó Tí Ṣe
àtúnṣe- Flee
- Passionate Appeal
- The Soul That Sinneth
- Wanted At All Cost
- Back To Life
- The Return
- Deadly Affair
- Glamour Girls
Ìgbésí Ayé Rẹ̀
àtúnṣeGloria jẹ́ ìyàwó fún Nobert Young, wọ́n sì ti bí ọmọ mẹ́ta.[19]
Àwọn Ìtọ́kàsi
àtúnṣe- ↑ enkay (2017-02-07). "Actress Gloria Young is 50 ...Plus photos from the birthday celebrations". Ivory NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02.
- ↑ Bodunrin, Sola (2017-02-08). "Nollywood actor stuns actress wife with exciting 50th birthday celebration (photos)". www.legit.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02.
- ↑ "I didn’t sleep with anyone to be movie star – Gloria Young". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-11. Retrieved 2019-12-04.
- ↑ "I’ve been having nightmares about Ibinabo — Gloria Anozie-Young". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-03-31. Retrieved 2019-12-02.
- ↑ "Nollywood alternative to prostitution, robbery says Gloria Anozie-Young". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2009-08-07. Retrieved 2019-12-02.
- ↑ "Gloria Anozie-Young Archives". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02.
- ↑ David, Tokunbo (2018-08-11). "I didn’t sleep with anyone to be movie star – Gloria Young". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02.
- ↑ 8.0 8.1 People, City (2018-09-24). "Winners Emerge @ 2018 City People Movie Awards". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-10.
- ↑ "Gloria Young". Africa Magic - Gloria Young (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02.
- ↑ Published. "Gloria Anozie-Young, others light up MUSON Festival". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02.
- ↑ "'Nollywood has many rivers to cross', Gloria Young | Encomium Magazine" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02.
- ↑ "Actress Gloria Young recalls her days as struggling journalist". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-02-23. Retrieved 2019-12-02.
- ↑ "Ẹda pamosi". guardian.ng. Archived from the original on 2019-12-02. Retrieved 2019-12-02.
- ↑ Banjo, Noah (29 October 2021). "FULL LIST: Ayinla, Omo Ghetto: The Saga bag multiple nominations at AMAA 2021". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 30 October 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedvanguardngr.com
- ↑ "A novelty football match for Gloria Young at 50". guardian.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 4 February 2017. Archived from the original on 2 December 2019. Retrieved 2 December 2019.
- ↑ enkay (7 February 2017). "Actress Gloria Young is 50 ...Plus photos from the birthday celebrations". Ivory NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2 December 2019.
- ↑ Bodunrin, Sola (8 February 2017). "Nollywood actor stuns actress wife with exciting 50th birthday celebration (photos)". www.legit.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2 December 2019.
- ↑ "Nollywood alternative to prostitution, robbery says Gloria Anozie-Young". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2009-08-07. Retrieved 2019-12-02.