Gobiri je ilekan tabi ilu kan ni orile ede ti amo si Nijiria. Adasile re waye ni orundun ateyinwa mokanla, Gobiri je okan lara awon ijoba atileba ni Ile Hausa