Godday Odagboyi Samuel je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. O je ọmọ ile ìgbìmò aṣojú ìjọba àpapọ̀ to n ṣoju àgbègbè Apa/ Agatu ti ipinle Benue ni ile igbimo asofin orile-ede kẹsàn-án. [1] [2] [3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe