Godwin Nikoi Kotey (tí wọ́n bí ní ọdún 1965 tí ó sì kú ní ọdún 2012) jẹ́ òṣèrékùnrin orílẹ̀-èdè Ghana, òǹkọ̀tàn àti olùdarí tó rí sí ìdàgbàsókè ilé-iṣẹ́ eré-ìdárayá.[1]

Godwin Kotey
Ọjọ́ìbíGodwin Nikoi Kotey
1965
Aláìsí2012
Orílẹ̀-èdèGhanaian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Southern Illinois
University of Ghana
Iṣẹ́Actor & Lecturer

Eto ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ó lọ sí Tema Senior High School àti Ghanata Senior High School. Lẹ́yìn náà ni ó lọ sí University of Ghana láti lọ gboyè ẹ̀kọ́ bachelor's degree àti masters nínú ẹ̀kọ́ theatre arts, ó sì ṣe Phd. ní Southern Illinois University Carbondale.[1][2]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

àtúnṣe

Godwin ṣiṣẹ́ olùkọ́ni ní University of Ghana, níbi tí ó ti kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nípa Performing Arts. Ní ọdún 1997 àti 1997 ó jẹ́ olùdarí fún Smash TV àti Taxi Driver ní ọdún 1999. Ní ọdún 2008 òun ni olùdarí iṣẹ́ àtinúdá fún ayẹyẹ 2008 Africa Cup of Nations.[3]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe

Orísun [4]

  • Police Officer
  • I Sing of A Well
  • Taxi Driver
  • The Scent of Danger
  • Etuo Etu Bare
  • Sodom and Gomorrah
  • Shoe Shine Boy

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "Godwin Nikoi Kotey (1965-2012) - Find A Grave...". www.findagrave.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-08-09. 
  2. "Actor Godwin Kotey laid to rest". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-08-09. 
  3. Online, Peace FM. "Ghanaian Actor And Producer Godwin Kotey Is Dead". Peacefmonline.com - Ghana news. Archived from the original on 2024-03-01. Retrieved 2020-08-09. 
  4. "Godwin Kotey". Nollywood Reinvented (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-08-09.