Ìpínlẹ̀ Gòngólà
(Àtúnjúwe láti Gongola state)
Ipinle Gongola jẹ́ ìpínlẹ̀ ìjọba ní Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ kí ó tó di pínpín sí Ìpínlẹ̀ Tàrábà àti Ìpínlẹ̀ Àdámáwá ní ọdún 1991. Ó jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọjọ́ kẹta Oṣù kejì ọdún 1976 lati ìgbèríko Àdámáwá àti Sàdáunà ní Ìpínlẹ̀ Àríwá-Apáìlàọrùn.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Gongola State of Nigeria Executive Council". Library of Congress Pamphlet Collection - Flickr. Retrieved 2014-05-11.