Ìhìnrere Jòhánù
(Àtúnjúwe láti Gospel of John)
Ìhìnrere Jòhánù ni iwe kerin akoko ninu majemu titun ti Bibeli Mimo. Ójé ara àwon ìwé Bibeli Mimo tí o soro lopolopo nípa ise ìránsé Jesu, a ti awo Johanu Aposteli ko ìwé yi.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |