Ìjọba

(Àtúnjúwe láti Government)

Ìjọba ni ikorajo ninu awujo kan, ile oloselu tabi agbajo to ni ase lati se ati fipase ofin, ilana, itele-ofin.

Detail from Elihu Vedder, Government (1896). Library of Congress Thomas Jefferson Building, Washington, D.C.

"Ijoba" ntoka si ijoba abele, isejoba oludalara to le ibile, onibinibi, tabi kariaye.

Ìjọba je "akojoegbe, to n joba lori agbegbe iselu kan",[1] "awon alase ninu awujo",[2] ati elo fun awon alase lati pase lori awujo.[3]Itokasi àtúnṣe