Gozel Green jẹ́ ilé iṣẹ́ ìránṣọ ti àwọn obìnrin ìgbàlódé tí àwọn ìbejì tí orúkọ wọn ń jẹ́ Sylvia Enekwe àti Olivia Okoji dá sílẹ̀ ní ọdún 2012, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìránṣọ ti ìgbàládé yí pẹ̀lú ìwúrí ará ọ̀tun láti ọ̀dọ̀ Ìyá tó bí wọn lọ́mọ tí òun náà jẹ́ aránṣọ jẹun.[1] Pupọ̀ nínú aṣọ tí àwọn ìbejì yí ń ran ni ó ma ń sè ìtàn kan tàbí òmíràn.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Contributor (2017-09-29). "Gozel Green: Spring Summer 2018 collection". Vogue.it. Retrieved 2020-02-06. 
  2. "Q&A With Gozel Green". OnoBello.com. Archived from the original on 2020-02-06. Retrieved 2020-02-06.