Grace Chinonyelum Anigbata (tí wọ́n bí ní 16 September 1998) jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tó máa ń kópa nínú eré-ìdárayá orí pápá àti abẹ́lé. Ó kópa nínú ìdíje triple jump ti 2019 African Games, níbi tí ó sì ti gba àmì-ẹ̀yẹ oníwúrà.[2][3][4] Ní ọdún 2016, Grace Anigbata di ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó dára jù lọ nínú eré-ìdárayá high jump, nígbà tó wà ní ọmọdún méjìdínlógún, tó sì fo ìwọ̀n 1.70 m.[5]

Grace Anigbata
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kẹ̀sán 1998 (1998-09-16) (ọmọ ọdún 26)
Height1.80 m[1]
Weight59 kg
Sport
Orílẹ̀-èdè Nigeria
Erẹ́ìdárayáAthletics
Event(s)Triple Jump
Achievements and titles
Personal best(s)14.02 m (Asaba 2018)

Ní ọdún 2018, ó jáwé olúborí nínú ìdíje ti African championships ní ìlú Asaba.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Athlete Profile ANIGBATA Grace Chinonyelum". 2019 AG official website. Archived from the original on 26 August 2019. Retrieved 26 August 2019. 
  2. "African Games (Athletics) Results - Women's Triple Jump Final". 2019 AG official website. Archived from the original on 26 August 2019. Retrieved 26 August 2019. 
  3. "Team Nigeria’s Anigbata grabs triple jump gold, as Ogundeji wins discus silver". punchng.com. Retrieved 27 August 2019. 
  4. "KIGEN AND RENGERUK LEAD CHARGE FOR KENYA ON FIRST DAY OF AFRICAN GAMES". iaaf.org. Retrieved 26 August 2019. 
  5. "Olamigoke wins 1st National title with SB of 16.70m". makingofchamps.com. Retrieved 7 August 2018.