Grace Apiafi (ti abini ojo ketadinlogbon Oṣù mokanla ni odun 1958) jẹ oṣere idaraya ti o wa lati Nigeria, ti o dije ninu shot put ati discus throw ni iṣẹ rẹ. Ó ṣojú fún orílẹ̀-èdè re west Áfíríkà ní ìdíje 1988 summer olympics ní ìlú Seoul, ní South Korea, níbi tí kò ti dé ìparí idije nanínú ìdíje méjèèjì.

Àwọn ìdíje àgbáyé àtúnṣe

Representing   Nàìjíríà
1979 African Championships Dakar, Senegal 2nd Shot put 13.24 m
1988 African Championships Annaba, Algeria 1st Discus throw 50.60
Olympic Games Seoul, South Korea 22nd Shot put 15.06 m
10th (q) Discus throw 49.84 m

External links àtúnṣe