Grace Nortey
Grace Nortey (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kìíní oṣù kejì ọdún 1937) jẹ́ òṣèrébìnrin ti orílẹ̀-èdè Ghana tó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àgbéléwò àti ti ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán.[1] Ó ti kópa nínú fíìmù àgbéléwò, eré orí-ìtàgé àti eré-oníṣe lóríṣiríṣi fún àádọ́ta ọdún, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àgbà ọ̀jẹ̀ inú fíìmù àgbéléwò ti orílẹ̀-èdè Ghana. [2]
Grace Nortey | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1 Oṣù Kejì 1937 Ghana |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1970s–present |
Àwọn ọmọ | 5 |
Ìgbésí ayé ara ẹni
àtúnṣeNortey bí ọmọ márùn-ún. Òun sì ni ìyá Sheila Nortey tí òun náà jẹ́ òṣèré.
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣeÀwọn fíìmù
àtúnṣeỌdún | Fíìmù | Ẹ̀dá-ìtàn | Ọ̀rọ̀ |
---|---|---|---|
1985 | Nana Akoto | ||
1992 | The Other Side of the Rich | Mrs. Ampofo | |
2006 | Frozen Emotion | Direct-to-video | |
2008 | Before My Eyes | Wummi | Direct-to-video |
2011 | Sinking Sands | Grandma | |
Ties That Bind | Church Member | ||
2015 | Beasts of No Nation | Old Witch Woman | |
2019 | P over D | Ayorkor | |
'95 | Old Woman |
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣe- Best Cameo Actress (Movie: "Adams Apple") - Ghana Movie Awards (2011[3])
- Excellence in Arts - Glitz Women of the Year Honours (2016)
- Lifetime Achievement Award - Black Star International Film Festival (BSIFF) Awards (2018)
- Legendary Award for Outstanding Contributions: Ghana Actors Entertainment Award (GAEA) - (2020)
- Outstanding Contribution to Women's Excellence in The Performing Arts - 3Music Awards Women's Brunch (2021)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Glitz top 100 inspirational women – Page 100 – Glitz Africa Magazine" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-28.
- ↑ "Grace Nortey Marks 87th Birthday". DailyGuide Network. 2024-02-05. Retrieved 2024-08-19.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0