Grace Omaboe (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹfà ọdún 1946), tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Maame Dokono, jẹ́ òṣèrébìnrin ti orílẹ̀-èdè Ghana, akọrin, àti olóòtú ètò orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán.[1][2][3] Ó fìgbà kan darí ilé àwọn ọmọ aláìníyàá ti Peace and Love Orphanage tí orúkọ rẹ̀ ti wá di Graceful Grace school ní ìlú Accra.[4] Wọ́n bu ọlá fún Omaboe àti àwọn mìíràn ní 3Music Awards fún akitiyan rẹ̀ nínú ilé ìṣẹ́ ìdárayá ní ìlú Ghana.[5]

Grace Omaboe
Ọjọ́ìbí10 June 1946 (1946-06-10) (ọmọ ọdún 78)
Birim North, Ghana
Orúkọ mírànMaame Dokono
Iṣẹ́Actress, singer, television personality, author and politician
Àwọn ọmọ6

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Grace Omaboe ní oṣù kẹfà ọdún 1946 ní ìlú Nyafuman, Birim North District, ní Ghana.

Ilé-ìwé Abetifi Girls School ni ó lọ.

Iṣẹ́ Omaboe àkọ́kọ́ tó ti farahàn nínú fíìmù wáyé nígbà tó kópa nínú fíìmù "Obra (TV drama)" èyí tí Ghana Broadcasting Corporation máa ń ṣàfihàn.[6] Omaboe fìgbà kan jẹ́ akọ̀tàn fún fíìmù orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán, Osofo Dadzie [7]

Grace Omaboe
Ọjọ́ìbí10 June 1946 (1946-06-10) (ọmọ ọdún 78)
Birim North, Ghana
Orúkọ mírànMaame Dokono
Iṣẹ́Actress, singer, television personality, author and politician
Àwọn ọmọ6

Grace Omaboe (born 10 June 1946), popularly known as Maame Dokono, is a Ghanaian actress, singer and television personality.[8][9][10] She ran the former Peace and Love Orphanage which is now Graceful Grace school in Accra.[4] Omaboe and others were honoured by the organisers of 3Music Awards for her achievement in the entertainment industry in Ghana.[11]

Early life

àtúnṣe

Grace Omaboe was born in June 1946 in Nyafuman, Birim North District, Ghana.

She attended Abetifi Girls School.

Omaboes first acting role was in the Akan Drama Series "OBRA" which was broadcast on GBC TV.[12]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

àtúnṣe

Omaboe fìgbà kan jẹ́ òǹkọ̀tàn fún Osofo Dadzi ní ọdún 1970, kó tó di pé Nana Bosompra gbà á níyànjú láti kópa nínú fíìmù Keteke.[13] Omaboe kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù orílẹ̀-èdè Ghana, ní èdè Akan àti èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ó kópa nínú fíìmù onítàn kúkurú kan, ìyẹn Kwaku Ananse.[14] Ní ọdún 2000, Omaboe kópa nínú ìdíje ìṣèlú gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ National Democratic Congress (NDC) ní New Abirem fún Birim North District ní apá Ìlà-Oòrùn agbègbè tó ti wá, èyí tí ó sì gbé ipò kejì.[15] Ní ọdún 2008, Omaboe ṣe àtìlẹyìn New Patriotic Party (NPP).[16] Omaboe fi ìdí ẹ̀ lélẹ̀ pé àwọn NDC parọ́ mọ́ òun, èyí sì mú gbé ọ̀rọ̀ náà lọ ilé-ẹjọ́ láti lọ jà fún ìdásílẹ̀ ilé àwọn ọmọ aláìníyàá rẹ̀ èyí tí wọ́n fi ẹ̀sùn ìwà ìbàjẹ́ kàn.[17] Àdàkọ:Better source needed Wọ́n ti ilé àwọn ọmọ aláìníyàá náà pa nítori àìgba ìwé-àṣẹ láti ṣiṣẹ́. [18] Omaboe jáwọ́ kúrò nínú ọ̀rọ̀ ìṣèlú ní ọdún 2016, tí ó sì sọ wí pé òṣèlú ń fi àkókò ẹni ṣòfò, ó ń kówó lọ, bẹ́ẹ̀ sì ni ó kún fún àwọn aláìṣòdodo ènìyàn.[19] Wọ́n yan Omaboe láti jẹ Ààrẹ àwọn adájọ́ fún 2017 Golden Movie Awards Africa (GMAA).[20][21]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe
  • Obra
  • Kwaku Ananse (2013) bí i Aso Yaa
  • I Surrender (1998) bí i Julie
  • P over D (2019) bí i Maame Serwaa
  • Children of The Mountain (2016) bí i Naana
  • Amerikafo (2018) bí i Grandma
  • Matters of the Heart (1993)
  • John and John (2017)
  • Expectations (1999) bí i Obaa Mercy
  • Aloe Vera (2020)

Personal life

àtúnṣe

Omaboe ti ṣe ìgbéyàwó ní ẹ̀ẹ̀mejì, èyí tí ìgbéyàwó náà ti forí ṣọ́pọ́n.[22] Ó ní ọmọ mẹ́fà, méjì wà ní United States, méjì wà ní Netherlands àwọn méjì yòókù sì wà ní Ghana.[23][24][25]

Omaboe ṣàlàyé pé òun fìgbà kan fẹ́ David Dontoh lásìkò tí wọ́n ń ṣe fíìmù Keteke àti Obra. Àwọn ènìyàn gbàgbọ́ pé wọ́n fẹ́ ara wọn fún ọdún mẹ́rin. Dontoh ò fi ìdí èyí múlẹ̀ rárá [26] àmọ́ ó ṣàlàyé pé ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ ni wọ́n, pàápàá jù lọ ìgbà tí Omaboe kọ ọkọ àkọ́kọ́ rẹ̀ sílẹ̀. [27] Onaboe àti Dontoh pínyà àmọ́ wọ́n ṣì ń bá ọ̀rẹ́ wọn lọ.[28][29]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Grace Omaboe Mom Dies At 105". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-27. 
  2. "Politics scares me now - Maame Dokono". www.myjoyonline.com. Retrieved 2019-03-02. 
  3. "In celebration of Grace Omaboe: Most talented Ghanaian entertainer". Graphic Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-12. Retrieved 2019-11-26. 
  4. 4.0 4.1 "Personality Profile: Grace Omaboe; A veteran Ghanaian actress – Today Newspaper" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-12-24. Retrieved 2020-04-03.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Theresa Ayoade, Akosua Adjepong, Daughters of Glorious Jesus, others honoured at 3Music Women's Brunch - MyJoyOnline.com". www.myjoyonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-03-08. 
  6. "Maame Dokono loses mother". Pulse Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-24. Retrieved 2021-05-27. 
  7. "Grace Omaboe, Biography, Age, Education, By The Fire Side, Net worth, Date Of Birth, Maame Dokono, Birthday » GhLinks.com.gh™" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-27. 
  8. "Grace Omaboe Mom Dies At 105". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-27. 
  9. "Politics scares me now - Maame Dokono". www.myjoyonline.com. Retrieved 2019-03-02. 
  10. "In celebration of Grace Omaboe: Most talented Ghanaian entertainer". Graphic Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-12. Retrieved 2019-11-26. 
  11. "Theresa Ayoade, Akosua Adjepong, Daughters of Glorious Jesus, others honoured at 3Music Women's Brunch - MyJoyOnline.com". www.myjoyonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-03-08. 
  12. "Maame Dokono loses mother". Pulse Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-24. Retrieved 2021-05-27. 
  13. "In celebration of Grace Omaboe: Most talented Ghanaian entertainer". Graphic Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-12. Retrieved 2019-04-13. 
  14. "Kwaku Ananse Film by Akosua Adoma Owusu". 2dots.co. Archived from the original on 1 December 2017. Retrieved 17 December 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  15. "Election 2000: Birim North Constituency". Peace FM Online. 14 August 2024. Archived from the original on 14 August 2024. Retrieved 19 August 2024. 
  16. "Maame Dokono defects to NPP". www.ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 30 November 2001. Retrieved 2017-06-15. 
  17. "NDC destroyed my life – Maame Dokono". www.justiceghana.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-08-08. Retrieved 2017-06-15. 
  18. "Court acquits and discharges Maame Dokono". Business Ghana. 6 August 2010. https://www.businessghana.com/site/news/general/119393/legal. 
  19. Essah, Helena (2016-03-22). "Maame Dokono: Politics is all full of lies". Ghana Live TV. Retrieved 2017-06-15. 
  20. "Grace Omaboe appointed head of jury for 2017 GMAA". www.ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 27 May 2017. Retrieved 2017-06-15. 
  21. "Grace Omaboe appointed head of jury for 2017 GMAA" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-03. 
  22. "I regret leaving my first husband – Maame Dokono". www.ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 30 October 2017. Retrieved 2019-04-13. 
  23. Juanita Sallah. "I wish I could do 'By the Fireside' again – Maame Dokono". starrfmonline.com. Retrieved 29 August 2015. 
  24. News Ghana (13 June 2015). "Veteran actress Grace Omaboe dazzles at Golden Movie Awards screening". newsghana.com.gh. Retrieved 29 August 2015. 
  25. Patrick Ayumu. "Maame Dokono was a "disaster" for NPP – Arthur K". starrfmonline.com. Archived from the original on 22 December 2015. Retrieved 29 August 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  26. Archived at GhostarchiveÀdàkọ:Cbignore and the Wayback MachineÀdàkọ:Cbignore: Àdàkọ:Cite AV mediaÀdàkọ:Cbignore
  27. "Maame Dokono explains break up with David Dontor". 26 November 2019. 
  28. "'I Broke up with David Dontoh Because I Couldn't Give Him a Child"-Maame Dokono Reveals". 30 March 2021. Archived from the original on 26 October 2021. Retrieved 15 July 2021.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  29. "My inability to give David Dontoh a child broke us up – Maame Dokono". 31 March 2021.