Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the fruits of the genus Vitis. Fún the European grapevine, ẹ wo: Vitis vinifera. Fún other uses, ẹ wo: Grape (disambiguation).

Girepu je eso ti a tun mo sí beri, ti eso igi ti o ni àjàrà ti eya Vitis. Girepu je oríṣi eso ti o wa non-climateric, o tun maan wa ni isupo.

Grapes
"Black" (dark blue) and "white" (light green) table grapes

Gbingbin eso yìí bere odun egbaarin ,ati wipe eso ti je ounje ti eniyan lati odun to tipe wa. A le je eso yìí ni tutu tàbí ni gbígbé(bi raisins,kurrant tabi sultans),girepu je eso ti o ni itumo asa pataki ni orilẹ ede àgbáyé ,pataki julo ninu otí waini sise. Awọn ohun ti a le fi Girepu se míràn je orisirisi Kanu, juice,vinegar ati ororo.