Greg Grunberg

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Gregory Phillip Grunberg (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù keje ọdún 1966) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Eric Weiss nínú eré ABC tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Alias, Matt Parkman nínú eré NBC tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Heroes, Temmin "Snap" Wexley nínú Star Wars: The Force Awakens àti Star Wars: The Rise of Skywalker, àti Phil nínú A Star Is Born. Ó farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré tí J. J. Abrams, ẹni tí ó jẹ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀ dárí bi àpẹẹrẹ, Felicity nínú Sean Blumberg. Ó tún ṣeré nínú eré Showtime tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Masters of Sex.

Greg Grunberg
Grunberg ní Phoenix Comic Fest ní ọdún 2018
Ọjọ́ìbíGregory Phillip Grunberg
11 Oṣù Keje 1966 (1966-07-11) (ọmọ ọdún 58)
Los Angeles, California
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1990–present
Olólùfẹ́Àdàkọ:Married
Àwọn ọmọ3

Ìpìlẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Grunberg ní ìlú Los Angeles, California, sínú ìdílé Sandy (née Klein) àti Gerry Grunberg[1][2] wọ́n sì tọ dàgbà ní ìlànà Júù.[3] Ó lọ ilé-ìwé University High School ní West Los Angeles.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Greg Grunberg Biography Archived May 22, 2011, at the Wayback Machine., Yahoo!. Retrieved March 2, 2016.
  2. Greg Grunberg profile, nndb.com. Retrieved November 2, 2013.
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named JewishFederations
  4. University High School 1984 yearbook, Uni Hi Education Foundation. Retrieved November 7, 2021.