Gregor Mendel
(Àtúnjúwe láti Gregor Johann Mendel)
Gregor Johann Mendel (July 20, 1822[1] – January 6, 1884) je ojise olorun ati onimosayensi ara Austria, to gbajumo leyin iku re gege eni pataki ninu sayensi tuntun genetics nitori agbeka ijogun iru maruloawon iwa kan pato ninu ogbin ewa popondo. Mendel fihan pe ijogun awon iwa wonyi untele awon ofin kan pato, ti won gba oruko re lojowaju. Bi ise Mendel yi se se pataki to ko je didamo ki o to di ibere orundun 20k. Itunwari alominira awon ofin wonyi ni won se ifilole sayensi odeoni ton unje genetiki.[2]
Gregor Johann Mendel marulo | |
---|---|
Ìbí | Heinzendorf bei Odrau, Silesia, Austrian Empire | Oṣù Keje 20, 1822
Aláìsí | January 6, 1884 Brno, Moravia, Austria-Hungary | (ọmọ ọdún 61)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Austria-Hungary |
Ẹ̀yà | German |
Pápá | Genetics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Abbey of St. Thomas in Brno |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Vienna |
Ó gbajúmọ̀ fún | Discovering genetics |
Religious stance | Roman Catholic |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ July 20 is his birthday; often mentioned is July 22, the date of his baptism. Biography of Mendel at the Mendel Museum Archived 2014-10-21 at the Wayback Machine.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedpb