Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè

(Àtúnjúwe láti Gross domestic product)

Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè (GIO) ni ona iwon gbogbo okowo orile-ede kan. Eyi ni iye owo itaja gbogbo oja ati isisefun to waye ninu bode orile-ede kan larin odun kan.

Ṣíṣe ìṣirò ìpawó orílẹ̀-èdè.