Gugulethu Sophia Mbatha-Raw ( /ˈɡɡ əmˈbætərɔː/;[1][2] tí a bí ní ọjọ́ Kínní oṣù kẹrin ọdún 1983) jẹ́ òṣèrébìnrin orílẹ̀ èdè Britain. Óbeẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣeré ní ational Youth Music Theatre àti ní Royal Academy of Dramatic Art, ó sì di gbájúmọ̀ká fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Juliet nínú eré Romeo and Juliet àti Octavia nínú Anthony and Cleopatra ní ọdún 2005 nínú Royal Exchange Theatre, Manchester.

Gugu Mbatha-Raw
Mbatha-Raw ní ọdún 2013
Ọjọ́ìbíGugulethu Sophia Mbatha-Raw
21 Oṣù Kẹrin 1983 (1983-04-21) (ọmọ ọdún 41)
Oxford, England
Ẹ̀kọ́Royal Academy of Dramatic Art (BA)
Iṣẹ́Òṣèrébìnrin
Ìgbà iṣẹ́2001 títí di ìsinsìnyí

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Bernstein, Abbie (30 May 2012). "Gugu Mbatha-Raw On 'Touch' Interview – EXCLUSIVE". buzzymag. http://buzzymag.com/gugu-mbatha-raw-on-touch-interview-exclusive. 
  2. "Gugu Mbatha-Raw Attempts to Put Together Mr. Potato Head". Vanity Fair. 3 February 2016. Archived from the original on 13 December 2021. Retrieved 12 January 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)Àdàkọ:Cbignore