Gulzar Group of Institutes jẹ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga ní Khanna, ìlú Ludhiana ní orílẹ̀ èdè India. Ilé ẹ̀kọ́ yii jẹ́ ti aladani, ó sì wà ní abẹ́ ilé ẹ̀kọ́ ti ìjọba Punjab Technical University, Jalandhar.