Haji ni irinajo lo si Mẹ́kkà. Lowolowo o je irinajo to tobijulo, o si je ikan ninu Opo marun Islamu ni pato ikarun. O se dandan fun eni to je mùsùlùmí lati lo si Haji lekan ni igbesiaye won.

Mosalasi Masjid al-Haram ti won ko sori kabaa ni MekkaItokasiÀtúnṣe