HTML
HTML to duro fun HyperText Markup Language je opagun kariaye.
Filename extension | .html, .htm |
---|---|
Internet media type | text/html |
Type code | TEXT |
Uniform Type Identifier | public.html |
Developed by | World Wide Web Consortium & WHATWG |
Type of format | Markup language |
Extended from | SGML |
Extended to | XHTML |
Standard(s) | ISO/IEC 15445 W3C HTML 4.01 W3C HTML 5 (draft) |
HTML je akanda ede Pataki ti a n lo lati ko webu ni pele n pele.
HTML ni orisirisi eroja ti a le lo lati we abi bo awon ara eya ara oun ti o wa ninu webu lati je ki o ri bi a se fe ki o ri. Fun apeere, a le lo lati je ki oro inu webu ko tobi abi ko kere abi lati kun ni orisirisi oda bi oda eweko, oda fun, abi dudu abi pupa. A tun le lo HTML lati je ki awon aworan, fidio ati oro ti o wa ninu webu ki o dun nwo loju nipa mimu ki o tobi tabi kere, tabi ki o tan yinyin tabi ki o dudu.
A le fi Jafa ati CSSS kun HTML lati jeki webu ko ni iwulo pupo ati ko le dun now loju si. Ti a ba fi CSSS kun HTML, a le yipada abi se atunse abi afikun bi webu se ma ri ti yo fi rewa ti yoo dun n wo loju. Ti a ba fi Jafa kun HTML, a o le e fi awon iwulo pupo kun webu wa. Fun apere, ti eniyan kan ba fi owo kan botini kan ni inu webu, opolopo n kan ti awon onimo ise ayarabi-asa fi si ori webu lo le yi pada si bi won se se eto re sibe.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Mozilla.org. (2023). HTML basics - Learn web development | MDN. [online] Available at: https://developer.mozilla.org/en-US/docs/Learn/Getting_started_with_the_web/HTML_basics [Accessed 22 Oct. 2023].