Habibur Rahman Khairabadi

Habibur Rahman Khairabadi (o tumọ si Mufti Habībur Rahmān; wọn bini ọjọ kọkanla, óṣu August, ọ̀dun 1933) jẹ̀ ọnimọ ẹsin musulumi[1] ati adajọ ti Mufti Darul Uloom Deoband. Arakunrin naa jẹ Alumnus ti Darul Uloom Mau, Mazahir Uloom ati ilè iwè giga musulumi ti Aligarh. Awọn iwè rè ni Ofin didu ẹran ati pataki yiyan zakat. Ónimọ ẹsin naa fi ọwọ si ófin ẹsin akọkọ lori jagigi jagan ni ọdun 2008[2].

Mawlānā, Mufti

Habībur Rahmān Khairābadi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kẹjọ 1933 (1933-08-11) (ọmọ ọdún 91)
Khairabad, Mau
Alma materMadrasa Ehya-ul-Uloom, Darul Uloom Mau, Mazahir Uloom, Aligarh Muslim University

Ìtan Ìgbèsi Àye Habibur Rahman Khairabadi

àtúnṣe

Habībur Rahmān Khairābadi ni wọn bini ọ̀jọ kọkanla, óṣu August, ọdun 1933 ni Khairabad lẹyin naa ni (Azamgarh)[3]. Habībur kẹkọ ni Madrasa Ehya-ul-Uloom ni Mubarakpur, Darul Uloom Mau ati Dārul Muballigheen ni Lucknow[4] . Ó kẹẹkọ jade lati Mazahir Uloom nibi to ti kẹẹko lori Sihah Sitta ati iwe Tafsir al-Baydawi[5] .

Habībur gba B.A ati M.A lati ilè iwè ẹsin musulumi ti Aligarh. O kẹkọ Sahih Bukhari ati Jami' al-Tirmidhi pẹlu Hussain Ahmad Madani; ati Al-Mutanabbi Dīwān pẹlu Meraj-ul-Haq Deobandi.

Lẹyin ẹkọ rẹ, Khairābadi ṣiṣẹ ólukọ ni Mahd-e-Millat ni Malegaon fun ọ̀dun mààrun lẹyin naa ni Idāra Maḥmudiyyah to wa ni Lakhimpur fun ọdun mèji[6] . Habibur Rahman darapọ̀ Madrasa Hayāt-ul-Uloom ni Moradabad nibi to ti ṣiṣẹ lori Islamic jurisprudence fun ọ̀dun mẹta lèèlogun[7].

Ni ọdun 1984, arakunrin naa ni a fi jẹ ólukọ ni Darul Uloom Deoband ti wọn si gbè lọ si ilè iwè Darul Ifta[8] . Ni Darul Uloom Deoband, Khairābadi kọ iwe lóri Islamic jurisprudence bi Al-Durr al-Mukhtar, Rasm al-Mufti ati Sirāji. Awọn akẹẹkọ rẹ ni Mufti ti Madrasa Shahi Salmān Mansoorpuri ati Shabbīr Aḥmad[9].

Ni ọdun 2008, Khairābadi fi ọwọ si ẹsin lati Darul Uloom Deoband eyi to lodi si Jagidijagan. Ofin naa sọpè:"Ẹsin Islam lodi si oniru jagijagan, aifini lọkan balẹ ati ipaniyan. Ofin to di ẹsin islam mu ni riran ara ẹni lọwọ lati ṣè dàadàà ti ko si gbeja ẹni kankan lori ṣiṣẹ tabi jagidigan. Ohan gèdè pè ofin ati ilana to wa ni Iwè Qur'an mimọ pe fifi ẹsun jagidijagan kan ẹsin bi islam to faramọ ifọkanbalẹ jẹ irọ̀. Ẹsin islam ni wọ̀n da kalẹ lati dèna óriṣiriṣi jagidijagan lati mu ifọ̀kanbalẹ ba gbogbó ayè"[10][11]. Ófin naa jẹ akọkọ ti wọn lo ni ilè iwè naa.

Awọn ìṣẹ rẹ

àtúnṣe

Habībur Rahmān kọ marginalia lori Jami' al-Tirmidhi ti akọle rẹ jẹ Hadīth al-misk al-shadhi[6]. Awọn iṣẹ rẹ to ku:

  • Hāshiya Fatāwa Rashīdiya (Marginalia lori Fatāwa Rashīdiya ti Rashid Ahmad Gangohi)
  • Masā'il-e-Qurbāni (Ọfin to wa ni didu ẹran)
  • Ramadan awr Uske Roze (Óṣu Ramadan ati gbigba awẹ)
  • Shab-e-Barāt awr Qur'ān (Shab-e-barat ni imọlẹ Quran)
  • Sharah Mufīd-ut-tālibīn (Marginalia lori Mufīd-ut-tālibīn)
  • Zakāt ki Ahmiyyat (Pataki Zakat)

Awọn Itọkasi

àtúnṣe
  1. "Scholars". Islamic Fiqh Academy India. Retrieved 2023-09-13. 
  2. "First Person". Force a complete news magazine on National Security. 2023-08-03. Retrieved 2023-09-13. 
  3. Muḥammadullah Qāsmi (December 2016) (in ur). Darul Uloom Deoband ki Jami' wa Mukhtasar Tārīkh (2nd ed.). Deoband: Shaykhul Hind Academy. p. 704-705. 
  4. Aftāb Ghāzi Qāsmi; Abdul Haseeb Qāsmi, Fuzala-e-Deoband Ki Fiqhi Khidmat, p. 350 
  5. Shahid Saharanpuri (2005) (in ur). Ulama e Mazahir Uloom aur unki Ilmi wa tasnīfi khidmāt. 1 (2nd ed.). Saharanpur: Maktaba Yādgār-e-Shaykh. pp. 275–276. 
  6. 6.0 6.1 Aftāb Ghāzi Qāsmi; Abdul Haseeb Qāsmi, Fuzala-e-Deoband Ki Fiqhi Khidmat, p. 351 
  7. Aftāb Ghāzi Qāsmi; Abdul Haseeb Qāsmi, Fuzala-e-Deoband Ki Fiqhi Khidmat, p. 143 
  8. Ziauddin Sardar; Merryl Wyn Davies (2008). Will America Change? (2008 ed.). Icon Books. p. 227. ISBN 9781840468793. https://books.google.com/books?id=iwYQAQAAMAAJ&q=Mufti+Habibur+Rahman. 
  9. Aftāb Ghāzi Qāsmi; Abdul Haseeb Qāsmi, Fuzala-e-Deoband Ki Fiqhi Khidmat, p. 352 
  10. "Deoband first: A fatwa against terror". Times of India. 1 June 2008. https://timesofindia.indiatimes.com/india/deoband-first-a-fatwa-against-terror/articleshow/3089161.cms. 
  11. Shishir Gupta (2012). Indian Mujahideen. Hachette UK. ISBN 9789350093757. https://books.google.com/books?id=v7Jp94ZaEekC&q=Mufti+Habibur+Rahman&pg=PT164.