Haile Selassie 1k
(Àtúnjúwe láti Haile Selassie I of Ethiopia)
Haile Selassie I | |
---|---|
Reign | 2 November 1930–12 September 1974 ( | ọdún 43 , ọjọ́ 314 )
Coronation | 2 November 1930 |
Predecessor | Zewditu I |
Successor | De jure Amha Selassie I (crowned in exile) |
Predecessor | Zewditu I |
Successor | Aman Andom (as Chairman of the Derg) |
Spouse | Empress Menen |
Issue | |
Princess Romanework Princess Tenagnework Asfaw Wossen Princess Zenebework Princess Tsehai Prince Makonnen Prince Sahle Selassie | |
Full name | |
Ras Tafari Makonnen | |
House | House of Solomon |
Father | Ras Makonnen Woldemikael Gudessa |
Mother | Weyziro Yeshimebet Ali Abajifar |
Born | Ejersa Goro, Ethiopia | 23 Oṣù Keje 1892
Died | 27 August 1975 Addis Ababa, Ethiopia | (ọmọ ọdún 83)
Religion | Ethiopian Orthodox Tewahedo |
Haile Selassie | |
---|---|
1st & 5th Chairman of the Organization of African Unity | |
In office 25 May 1963 – 17 July 1964 | |
Arọ́pò | Gamal Abdel Nasser |
In office 5 November 1966 – 11 September 1967 | |
Asíwájú | Joseph Arthur Ankrah |
Arọ́pò | Joseph-Désiré Mobutu |
Haile Selassie 1k (Ge'ez: ኃይለ፡ ሥላሴ, "Power of the Trinity"[1]) (23 July 1892 – 27 August 1975), oruko abiso Tafari Makonnen,[2] lo je oba oriite Ethiopia lati 1916 de 1930 ati Obaluaye ile Ethiopia lati 1930 de 1974. Ajogun iran-oba to fa ibere re wa lati orundu 13k, ati lati ibe gegebi asa de odo Oba Solomoni ati Ayaba Makeda, Ayabaluaye ile Aksum, to gbajumo ninu asa Abrahamu bi Ayaba ile Sheba. Haile Selassie je eni pataki ninu itan Ethiopia ati Afrika .[3][4]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Gates, Henry Louis and Appiah, Anthony. Africana: The Encyclopedia of the African and African American Experience. 1999, page 902.
- ↑ Melvin Eugene Page, Penny M. Sonnenburg (2003). Colonialism: an international, social, cultural, and political encyclopedia. Volume 1. ABC-CLIO. p. 247. ISBN 9781576073353. http://books.google.co.uk/books?id=qFTHBoRvQbsC&pg=PA247&dq=Haile+Selassie+I+born+TAFARI&client=firefox-a#v=onepage&q=Haile%20Selassie%20I%20born%20TAFARI&f=false. Retrieved 2009-10-05
- ↑ Erlich, Haggai. The Cross and the River: Ethiopia, Egypt, and the Nile. 2002, page 192.
- ↑ Murrell, Nathaniel Samuel and Spencer, William David and McFarlane, Adrian Anthony. Chanting Down Babylon: The Rastafari Reader. 1998, page 148.