Halima Atete

Òṣéré orí ìtàgé

Halima Yusuf Atete tí a tún mọ̀ ní Halima Atete(tí a bí ní ọjọ́ 26 Oṣù kọ́kànlá Ọdún 1988) jẹ́ òṣèré fiimu Nàìjíríà àti agbéré-jáde, tí a bí tó sì dàgbà ní ìlu Maiduguri, Ìpínlẹ̀ Borno.[1] Halima Atete gbajúmọ̀ ní sinimá kannywood fún ipa tí ó ma n sáábà kó nígbà gbogbo bíi aláìṣedédé àti olójòwú.[2] Ó darapọ̀ mọ́ kannywood ní ọdún 2012, ó sì ṣe àkọ́kọ́ eré rẹ̀ nínu fiimu Asalina (Orísun mi) fiimu kan tí ó tọwọ́ rẹ̀ wá. Lẹ́hìn tí ó kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fiimu bíi Kona Gari, Asalina, Dakin Amarya, ó gba àmì-ẹ̀yẹ fún ti òṣèré tí ó dára jùlọ níbì ayẹyẹ City People Entertainment Awards ní ọdún 2013.[3]

Halima Atete
Ọjọ́ìbíHalima Yusuf Atete
26 Oṣù Kọkànlá 1988 (1988-11-26) (ọmọ ọdún 35)
Maiduguri, Ipinle Borno, Naijiria
Orílẹ̀-èdèNaijiria
Iṣẹ́Osere Itage, Agberejade
Ìgbà iṣẹ́2012 - lowolowo
Gbajúmọ̀ fúnIpa re ninu Dakin Amarya

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ àtúnṣe

A bí Halima Atete ní Maiduguri, Ìpínlẹ̀ Borno. Ó lọ sí ilé-ìwé alákọ́bẹ̀rẹ̀ Maigari. Ó parí ilé-ìwé girama ní Yerwa Government Day Secondary School. Halima gba oyè-ẹ̀kọ́ ní òfin sharia àti ti ìlú. Halima darapọ̀ mọ́ kannywood ní ọdún 2012 [4], ó sí ti se àgbéjáde orísirísi àwọn eré àgbéléwò bíi Asalina àti Uwar Gulma.[5]

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ àtúnṣe

Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ẹ̀ka Àbájáde
2013 City People Entertainment Awards Òṣèré tuntun tó dára jul̀ọ Gbàá
2014 City People Entertainment Awards Òṣèré tó dára jul̀ọ ní ipa àtìlẹyìn[6] Gbàá
2017 African Voice Òṣèré tó dára jul̀ọ Wọ́n pèé
2017 City People Entertainment Awards Òṣèré tó dára jul̀ọ[7] Gbàá
2018 City People Entertainment Awards Kannywood Face[8] Gbàá

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀ àtúnṣe

Àkọ́lé Ọdún
Wata Hudu ND
Yaudarar Zuciya ND
Asalina (My Origin) 2012
Kona Gari 2012
Dakin Amarya 2013
Matar Jami’a 2013
Wata Rayuwa 2013
Ashabu Kahfi 2014
Ba’asi 2014
Bikin Yar Gata 2014
Maidalilin Aure 2014
Soyayya Da Shakuwa 2014
Alkalin Kauye 2015
Bani Bake 2015
Kurman Kallo 2015
Uwar Gulma (Mother of Gossip) 2015
Mu’amalat 2016
Igiyar Zato 2016

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Halima Yusuf Atete [HausaFilms.TV - Kannywood, Fina-finai, Hausa Movies, TV and Celebrities]". hausafilms.tv. HausaTV. Retrieved 27 August 2019. 
  2. Askira, Aliyu (1 December 2014). "It’s all gossip; I am not having an affair with Ali Nuhu – Halima Atete". Blueprint. Retrieved 27 August 2019. 
  3. Aiki, Damilare (16 July 2013). "2013 City People Entertainment Awards: First Photos & Full List of Winners". BellaNaija. Retrieved 27 August 2019. 
  4. "Who Is Halima Atete? Biography| Profile| History Of Kannywood Actress Halima Yusuf Atete - Page 2 of 2". Daily Media Nigeria. Daily Media Nigeria. 1 August 2017. Archived from the original on 27 August 2019. Retrieved 27 August 2019. 
  5. Lere, Muhammad (31 May 2014). "My new film "Uwar Gulma" will be a hit - Halima Ateteh - Premium Times Nigeria". Premium Times. Premium Times. Retrieved 27 August 2019. 
  6. Lere, Muhammad (1 January 2015). "Kannywood's finest, worst moments of 2014 - Premium Times Nigeria". Premium Times. Premium Times. Retrieved 27 August 2019. 
  7. Emmanuel, Daniji (18 October 2017). "Full List Of Winners At The 2017 City People Movie Awards". City People Magazine. Retrieved 27 August 2019. 
  8. People, City (24 September 2018). "Winners Emerge @ 2018 City People Movie Awards". City People Magazine. Retrieved 27 August 2019.