Haimatu Àyinde jẹ àkọṣẹmọṣẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 16, óṣu May ni ọdun 1995. Arabinrin naa ṣere fun Eskilstuna United DFF ati team awọn obinrin lapapọ gẹgẹbi Midfielder. Arabinrin naa tifi igba kan ṣere fun Western New York ni United States ati Delta Queens ni órilẹ ede naigiria[1][2][3][4].

Halimatu Ayinde
Personal information
OrúkọHalimatu Ibrahim Ayinde
Ọjọ́ ìbí16 Oṣù Kàrún 1995 (1995-05-16) (ọmọ ọdún 29)
Ibi ọjọ́ibíKaduna, Nigeria
Ìga1.65m
Playing positionMidfielder
Club information
Current clubEskilstuna United DFF
Number18
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Delta Queens
2015–2016Western New York Flash9(1)
2016FC Minsk (women)5(4)
2018Asarums IF FK22(4)
2019-Eskilstuna United DFF38(0)
National team
2010–2012Nigeria women's national under-17 football team6(4)
2014Nigeria women's national under-20 football team6(0)
2015–Nigeria women's national football team12(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 01:45, 20 June 2019 (UTC).

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 17 June 2015

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Halimatu yege ninu ere idije awọn obinrin ilẹ Afirica to waye ni ọdun 2014.Elere naa kopa ninu 2015 Cup FIFA awọn obinrin agabaye nibi ti o ti jẹ aṣoju fun team apapọ orilẹ ede naigiria[5].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.playmakerstats.com/player.php?id=417507
  2. https://ng.soccerway.com/players/halimatu-ayinde/150702/
  3. https://fbref.com/en/players/e29e3055/Halimatu-Ayinde
  4. https://www.eurosport.co.uk/football/halimatu-ayinde_prs332036/person.shtml
  5. https://m.football-lineups.com/footballer/102031/Womens-World-Cup-Canada-2015/Nigeria