Hamdya Abass
Personal information
Ọjọ́ ìbíọjọ́ kinni oṣù Kẹjọ ọdún 1982
Playing positionAsọ́lé
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Ghatel Ladies
National team
Ghana7(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 10 September 2007 (before the 2007 FIFA Women's World Cup)

Hamdya Abass tí a bí ní ọjọ́ kinni oṣù Kẹjọ ọdún 1982 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin àgbáyé ti ilẹ̀ Ghana kan tí ó dúró gẹ́gẹ́ bí asọ́lé . Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti ẹgbẹ́ àwọn obìnrin agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède Ghana . Ó wà lára àwọn tí ó kópa pẹ̀lú 2007 FIFA Women's World Cup . Nípa ikọ̀ ẹgbẹ́ ó ṣeré fún Ghatel Ladies ní Ghana. [1]

Wo eléèyí ná

àtúnṣe
  • Àkójọ àwọn agbábọ́ọ̀lù àgbáyé ti àwọn obìnrin Ghana

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Empty citation (help) 

Àdàkọ:Ghana squad 2007 FIFA Women's World CupÀdàkọ:Ghana squad 2007 FIFA Women's World CupÀdàkọ:Authority control