Hanks Anuku
Òṣéré orí ìtàgé
Hanks Anuku tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1960 (12 May 1960)[1][2] jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó máa ń kópa nínú sinimá àgbéléwò èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Ìgbò [3][4] As of 2017, Anuku was naturalized and became a Ghanaian.[5]
Hanks Anuku | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1960 Ibadan |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Auchi Polytechnic |
Iṣẹ́ | òṣèré |
Ìgbà èwe rẹ̀
àtúnṣeAnuku lọ sí ilé-ìwé Loyola College, ní ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí ní ilé-ìwé Auchi Polytechnic in 1981,[6] and he was born 1960 in Ibadan.[2]
Àtòjọ àwọn sinimá-àgbéléwò tí ó ti kópa
àtúnṣe- Broad Daylight (2001)
- Bitter Honey (2005)
- The Captor (2006)
- Men on Hard Way (2007)
- Fools on the Run(2007)
- Desperate Ambition(2006)
- My Love
- Wanted Alive
- Rambo
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2024-06-11. Retrieved 2024-06-11.
- ↑ 2.0 2.1 Ikeru, Austine (19 January 2018). "Biography & Net Worth of Nollywood Actor Hanks Anuku". Austine Media. Archived from the original on 2019-01-19. Retrieved 2019-01-19.
- ↑ http://www.vanguardngr.com/2011/06/hanks-anuku-transforms/
- ↑ https://www.imdb.com/name/nm2116371/
- ↑ "Nollywood actor, Hanks Anuku exits Nigeria, turns Ghanaian - Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 2017-03-05. https://www.vanguardngr.com/2017/03/nollywood-actor-hanks-anuku-exits-nigeria-turns-ghanaian-name-nana-kwame-fifi-kakra/.
- ↑ modern ghana retrieved 13 March 2015