Hannah Ojo Ajakaye
Hannah Ojo Ajakaiye jẹ́ akòròyìn orílé èdè Nàìjíríà. Wọ́n yan-an gege bí Print Science journalist fún ọdún 201 láti gbà àmi ẹ̀yẹ Nigeria Academy Of Science, èyí tí ó sì gbà àmi ẹ̀yẹ náà.[1]
Ìgbé Ayé
àtúnṣeOjo ko gbọyè láti ilẹ ìwé Fásitì tí Ọbáfẹ́mi Awólowó tí ilé -Ifè ní orílé èdè Nàìjíríà.[1]
Ní ọdún 2016, Ojo gbà ẹbùn fún Most Innovative Reporting ni Nigerian Media Merit Award (NMMA) ni ipinlẹ Èkó.[1][2]
Ó jẹ ẹbùn ni Nigerian Academy of Science Media Awards ní Print Science Journalist of the year ní ọdún 2017.[1] Ó gbà àmi Newscorp Fellowship. Ó tún gbà àmi ẹ̀yẹ kan ní ọdún 2018 ni àpérò àwọn Akòròyìn Reham Al-Farra.[3][4]
Ó jẹ́ ọmọ ilé-ìwé gíga tí Ẹ̀ká Amẹ́ríkà tí Ilé-iṣẹ́ Àtẹ̀jade Àjèjì tí Ilé-iṣẹ́ Ijabọ lórí ìfipàgbé ọmọ ènìyàn. Ó jẹ́ mímọ̀ gẹ́gẹ́ bí Akòròyìn fún osù kẹwàá ọdún 2018 ní International Justice Network.[5][6] Hannah sí tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ TruthBuzz ní International Center fún àwọn Akọ̀ròyìn (ICFJ).[7]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 "The Nation’s Hannah Ojo wins Academy of Science Award". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-25. Retrieved 2021-12-02.
- ↑ "The Nation Harvests 13 Awards At NMMA 2016". The Elites Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-12-19. Retrieved 2021-12-02. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Ojo The Nation's reporter named UN journalism fellow". Media Career Services (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-07-23. Archived from the original on 2021-12-02. Retrieved 2021-12-02.
- ↑ Nations, United. "Hannah Ojo - Nigeria | Nations Unies". United Nations (in Èdè Faransé). Retrieved 2021-12-02.
- ↑ "Journalist of the month: Hannah Ojo". International Journalists' Network (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-02.
- ↑ "Hannah Ojo Declared The Journalist of The Month". Institute for Media and Society (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-10-31. Archived from the original on 2021-12-02. Retrieved 2021-12-02.
- ↑ "ICFJ TruthBuzz Fellow aims to tackle misinformation in Nigeria". شبكة الصحفيين الدوليين (in Èdè Árábìkì). Retrieved 2021-12-02.