Harqma

Ọbẹ̀ ọ̀yà ní Apá Àríwá ilẹ̀ Gúúsù

Harqma jẹ́ ọbẹ̀ tàbí ata tí a sè nípa lílo itan ọ̀yà.[1][2] Ó wọ́pọ̀ ní agbègbè Maghreb ti Àríwá ilẹ̀ Áfíríkà.[1][2] Harqma sábàá máa ń di jíjẹ lásìkò Ramadan, gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ láti já àwẹ̀ tàbí sínu lẹ́yìn tí oòrùn bá wọ̀.[1] Itan ọ̀yà sábàá máa ń jẹ́ lílò gẹ́gẹ́ bí ohun èlò.[1][2] Ó ti di dídábàá pé harqma wá láti Middle Ages.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Wright 2011
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Wright 2012