Èdè Sua

(Àtúnjúwe láti Harshen Sua)

Sua, tí àwọn ẹ̀yà míràn mọ̀ sí Mansoanka tàbí Kunante,[1] jẹ́ èdè Niger–Congo kan tí wọ́n ń sọ ní agbègbè Mansôa ti orílẹ̀ èdè Guinea-Bissau.[2]

Sua
Mansoanka
Sísọ níGuinea-Bissau
Ọjọ́ ìdásílẹ̀2016
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀17,600
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3msw

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Wilson, William André Auquier. 2007. Guinea Languages of the Atlantic group: description and internal classification. (Schriften zur Afrikanistik, 12.) Frankfurt am Main: Peter Lang.
  2. Güldemann, Tom (2018). "Historical linguistics and genealogical language classification in Africa". In Güldemann, Tom. The Languages and Linguistics of Africa. The World of Linguistics series. 11. Berlin: De Gruyter Mouton. pp. 58–444. doi:10.1515/9783110421668-002. ISBN 978-3-11-042606-9.