Hauwa Maina
Òṣéré orí ìtàgé
Hauwa Maina fìgbà kan jẹ́ òṣèrébìnrin tó máa ń ṣe fíìmù Hausa, àti aṣàgbéjáde fíìmù tó kópa nínú fíìmù Queen Amina of Zazzau. Ó kú látàrí àìsàn kan ní ilé-ìwòsàn kan ní Kano ní 2 May 2018.[1]
Hauwa Maina | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Borno State |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Kaduna State polytechnic |
Iṣẹ́ | Kannywood actress, Producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1998-2018 |
Àwọn ọmọ | 2 |
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
àtúnṣeÓ fìgbà kan jẹ́ akọ̀wé-gbogboogbò ti local hausa association of female producers. Ìsàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ wáyé nínú fíìmù Tuba, lẹ́yìn náà, ó kópa nínú bayajida, èyí tó jẹ́ fíìmù ajẹmọ́tàn tí wọ́n fi ń kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ìwé.[2] Ó ní ilé-iṣẹ́ aṣàgbéjáde fíìmù kan, tí ó sọ ní Ma'inta Enterprises Limited. Ilé-iṣẹ́ yìí ti ṣàgbéjáe ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù bí i Gwaska, Sarauniya Amina àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[3][4][5]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣe- Tuba
- Queen Amina of Zazzau[6]
- Bayajida
- Sarauniya Amina
- Gwaska and Maina
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ tó gbà
àtúnṣeÀwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Lere, Mohammed (2018-05-02). "Kannywood actress, Hauwa Maina, is dead". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-05.
- ↑ Liman, Abubakar Aliyu (5 September 2019). "Memorializing a Legendary Figure: Bajajidda the Prince of Bagdad in Hausa Land". Afrika Focus 32 (1). doi:10.21825/af.v32i1.11787.
- ↑ Blueprint (2014-03-24). "We want to tell our African stories in Hausa movies – Hauwa Maina". Blueprint (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Blueprint Newspapers Limited. Retrieved 2022-08-05.
- ↑ "Hail of tributes trail late Hauwa Maina, Kannywood celebrated actress". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-04. Retrieved 2022-08-05.
- ↑ Edubi, Omotayo (2018-05-03). "Kannywood actress, Hauwa Maina, is dead". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-05.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:02
- ↑ "Kannywood actress Hauwa Maina is dead". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-03. Retrieved 2022-08-05.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedEdubi2