Hayat al-Sahaba

ìsọníṣókí ìtàn nípa àwọn ọmọ lẹ́yìn Ànọ́bì Muhammed
(Àtúnjúwe láti Hayat-al-Sahaba)

Hayat al-Sahaba (Lárúbáwá: حياة الصحابة‎) jẹ́ ìwé Lárúbáwá tí Yusuf Kandhlawi kọ.[1] Wọ́n parí kíkọ ìwé yìí ní ọdún 1959, tí wọ́n sì fẹ̀ ẹ́ lójú sí abala mẹ́rin pẹ̀lú àwọn àfikún àti ìtọ́ka ìbẹ̀rẹ̀ láti ọwọ́ Abul Hasan Ali Hasani Nadwi àti Abd al-Fattah Abu Ghudda. Wọ́n kọ́kọ́ ṣàtẹ̀jáde ìwé náà fún Tablighi Jamaat.[2] Ó dá lórí àwọn orísun láti inú Hadith, ìtàn, àti ìtàn ìgbésí-ayé Muhammad àti àwọn alábàárìn rẹ̀( Sahaba). Ìwé náà ní orí mọ́kàndínlógún, tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì ń tọ́ka sí àwọn alábàárìn rẹ̀.[3]

Hayat al-Sahaba
Fáìlì:Cover of Hayat al-Sahaba.png
English cover
Olùkọ̀wéYusuf Kandhlawi
Àkọlé àkọ́kọ́حياة الصحابة
CountryIndia
LanguageArabic
SubjectCompanions of the Prophet
GenreBiography
Publication date
1959
Media typePrint
ISBNÀdàkọ:ISBNT Zam Zam Publishers
OCLC21989323
297/.64 full
LC ClassBP75.5.K313 1991

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Kajee, Imraan; Kajee, Moosa (2018) (in en). The legacy of the Ulama of Deoband. South Africa: Spiritual Light. pp. 55. https://spirituallight.co.za/node/141. Retrieved 7 March 2023. 
  2. Àdàkọ:TDV Encyclopedia of Islam
  3. Àdàkọ:Cite thesis