Helon Habila

Akéwì ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Helon Habila (ojoibi 1967) je olukowe omo ile Naijiria ti arakunrin naa gba ẹbun ti Caine ni ọdun 2001[1][2].

Helon Habila
Helon Habila, Göteborg 2010
CitizenshipNaijiria
Notable awardsCaine Prize
Website
http://www.helonhabila.com/

Ígbèsi Àyè Àrakunrin naa

àtúnṣe

Helon Habila ni a bini Kaltungo,ipinlẹ Gombe, ilẹ Naigiria[3].

Ni ọdun 2002, Habila lọsi ilú England ni ọdun 2002 ti arakunrin naa di fellow ti akọwè ilẹ africa ni ilè iwè giga ti East Anglia[4]. Ni ọdun 2005, Chinua Achebe pè Habila lati di fellow rẹ akọkọ ni college ti Bard[5].

Lati óṣu July 2013 di óṣu June 2014 Habila di fellow ti DAAD Fellow ni Berlin, Germany. Arakunrin naa ni wọn fi ṣè adajọ ninu ẹbun ti Etisalat lori literature ni ọdun 2016[6].

Helen kẹẹkọ lóri èdè gẹẹsi ati imọ literature ni ilè iwè giga ti jos lẹyin naa lo ṣiṣẹ ólukọ ni ninu Federal polytechnic ti Bauchi[7].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

àtúnṣe

Ni ọdun 2000 Ami ẹyẹ ti ẹgbẹ awọn ólórin ti ilẹ Naigiria apapọ ewi[8]. Ni ọdun 2001 Ẹbun ti Caine, "Love Poems"[9]. Ni ọdun 2003, Ẹbun ti Commonwealth awọn akọwè ti ilẹ africa, Waiting for an Angel. Ni ọdun 2007 Ẹbun ti Emily Clark Balch, "The Hotel Malogo"[10]. Ni ọdun 2008 Ami ẹyẹ ti Library of Virginia Literary fun for Fiction, Measuring Time[11]. Ni ọdun 2011, Ẹbun ti Commonwealth awọn akọwè Oil on Water[12]. Ni ọdun 2012 Ami ẹyẹ ti iwè Orion, Oil on Water[13]. Ni ọdun 2020, Ẹbun ti James Tait Black Memorial, Travelers[14][15].