Henry Akubuiro jẹ́ akọ̀rọ̀yìn àti àti òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]

Ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Akubuiro kàwé gboyè nínú ìmò Englisi ni Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Ímò, Owerri ni ọdun 2003.[2][3] Ó bèrè isé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọ̀rọ̀yìn nígbà tó sì jẹ́ ọmọ ilé-ìwé Yunifásitì ìpínlè Imo, níbi tí ó ti dá "editor of The Elite—the student newspaper in Imo State University" àti "The Imo Star—the newspaper of the Student Union Government" kalẹ̀. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ BBC World Service fún olúborí ìdíje láàrín àwọn ọ̀dọ́ akàròyìn àti ní ìdíje ìkọ̀wé tí ẹ̀ka ìjọba fún ètò ẹ̀kọ́ àti eré ìdáyará dá kalẹ̀.[2][3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Jaafar, Jaafar (12 July 2017). "Journalist Henry Akubuiro's intriguing view of the seedy side of Lagos". Daily Nigerian. Retrieved 27 October 2022. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. 2.0 2.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Premium
  3. 3.0 3.1 Akubuiro, Henry (24 September 2014). "Not so much of me chose to be a literary journalist – Akubuiro". Blueprint. Retrieved 27 October 2022.