Henry Dunant
Jean Henri Dunant (May 8, 1828 – October 30, 1910), aka Henry Dunant, je ara Swiss onisowo ati alakitiyan awujo. Nigba irinajo owo to se ni 1859 o ri esi Ija Solferino ni Italy loni. O ko gbogbo iriri re sile ninu iwe to pe ni A Memory of Solferino eyi lo fa idasile Igbimo Kariaye Agbelebu Pupa (ICRC) ni 1863. Iwe Ipinnu Geneva odun 1864 duro lori adaro Dunant. Ni odun 1901 o gba Ebun Nobel Alafia akoko pelu Frédéric Passy.
Henry Dunant | |
---|---|
Dunant as an elderly man | |
Ọjọ́ìbí | Jean Henri Dunant 8 Oṣù Kàrún 1828 Geneva, Switzerland |
Aláìsí | October 30, 1910 Heiden, Switzerland | (ọmọ ọdún 82)
Orílẹ̀-èdè | Swiss |
Iṣẹ́ | social activist, businessman, writer |
Gbajúmọ̀ fún | Founder of the Red Cross |
Parent(s) | Jean-Jacques Dunant Antoinette Dunant-Colladon |
Awards | Nobel Peace Prize (1901) |
Itokasi
àtúnṣe
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |