Hepatocellular carcinoma

Hepatocellular carcinoma (HCC), tí a tún pè ní malignant hepatoma, jẹ́ àrùn jẹjẹrẹ inú ẹ̀dọ tó wọ́pọ̀.

Hepatocellular carcinoma
Hepatocellular carcinomaHepatocellular carcinoma in an individual who was hepatitis C positive. Autopsy specimen.
Hepatocellular carcinomaHepatocellular carcinoma in an individual who was hepatitis C positive. Autopsy specimen.
Hepatocellular carcinoma in an individual who was hepatitis C positive. Autopsy specimen.
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta
ICD/CIM-10C22.0 C22.0
ICD/CIM-9155 155
MedlinePlus000280

Àwọn ìdí tí àrùn yìí lè fi wáyé ní nípasẹ̀ àkóràn kòkòrò jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ (Jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ B tàbí  C), àwọn ohun tó lòdì sára bíi ògógóró tàbí  aflatoxin, àwọn ìpò bíi  hemochromatosis àti alpha 1-antitrypsin deficiency or NASH.[1]

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Kumar V, Fausto N, Abbas A (editors) (2015).

Ìwé àkàsíwájú si àtúnṣe