Herbert Macaulay

Oníwé-Ìròyín

Herbert Samuel Heelas Macaulay (November 14, 1864May 7, 1946) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ọmọ-ọmọ Bíṣọọ́ọ̀bù Samuel Ajayi Crowther ní Herbert Macaulay jẹ́. A bí i ní ọdún 1864. Ó gboyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ẹ̀rọ lórílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ó dá ẹgbẹ́-òṣèlú sílẹ̀ lọ́dún 1923. Ó kú ní ọdún 1946 níbi ti ó ti n ṣe ìpolongo ìbò.