Herbert Simon
Olóṣèlú
Herbert Alexander Simon (June 15, 1916 – February 9, 2001) je ara Amerika asesayensi oloselu, aseitokowo, aseoroawujo, ati aseorookan, ati ojogbon ni Carnegie Mellon University—ti iwadi po to be lat cognitive psychology, cognitive science, computer science, public administration, economics, management, philosophy of science, sociology, ati political science. Simon gba Ebun Nobel 1978 ninu ọ̀rọ̀-òkòwò.
Herbert Simon | |
---|---|
Ìbí | Milwaukee, Wisconsin, USA | Oṣù Kẹfà 15, 1916
Aláìsí | February 9, 2001 Pittsburgh, Pennsylvania, USA | (ọmọ ọdún 84)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | United States |
Pápá | Artificial Intelligence Cognitive psychology Computer science Economics Political science |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Carnegie Mellon University University of California, Berkeley Illinois Institute of Technology |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Chicago |
Doctoral advisor | Henry Schultz |
Doctoral students | Edward Feigenbaum Allen Newell David Bree |
Ó gbajúmọ̀ fún | Logic Theory Machine General Problem Solver Bounded Rationality |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Turing Award 1975 Nobel Prize in Economics 1978 National Medal of Science 1986 von Neumann Theory Prize 1988 |
Religious stance | Unitarian |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |