Heritage Banking Company Limited
Heritage Bank Plc., tí a tún n pè ní Heritage Bank, jé̩ ilé ìfowopamọ. O jẹ ọkan lara awọn ile ifowopamọ ti gbogbo-gbo ti Ile Ifowopamọ apapọ ti Naijiria fi ọwọ si, tii ṣe akoso ọrọ ifowopamọ ni Naijiria,[1] pẹlu aṣẹ iṣiṣẹ, lati ṣe iduna dura eto ifowopamọ, eto ifowopamọ ti ayelujara, eto ifowopamọ onidokowo ati amojuto nkan ini; olu ile iṣẹ wọn wa ni 292B Ajose Adeogun Street, Victoria Island, Ẹ̀kọ́, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà.
Type | Public company by shares |
---|---|
Founded | 2012 |
Headquarters | 292B Ajose Adeogun Street, Victoria Island, Lagos, Lagos State, Nigeria |
Area served | Nigeria |
Key people |
|
Industry | Financial services |
Products | Banking and financial services |
Total assets | US$1.7+ billion (NGN:483.4 billion) (Dec 2015) |
Employees | 4000 |
Website | Homepage |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "List of Licensed Commercial Banks In Nigeria". Central Bank of Nigeria. Retrieved 4 November 2014.