Herring smelt
Herring smelts tàbí àwọn argentine jẹ́ ẹbí, Argentinidae, ti òkún smelts. Ìrísí wọn dàbí ti smelts (ẹbí Osmeridae) ṣùgbọ́n ẹnu won kéré díẹ̀.
Herring smelt | |
---|---|
Argentina sphyraena | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | |
Ẹgbẹ́: | |
Ìtò: | |
Ìdílé: | Argentinidae Bonaparte, 1838
|
Genera | |
Wọ́n maa ń rí wọ́n nínú òkun káàkiri gbogbo agbayé. Wọ́n jẹ́ ẹja kékeré, tí wọ́n maa ń dàgbà tó bí 25 centimetres (9.8 in) ní gígùn, yàtọ̀ sí argentine títóbi, Argentina silus, t́ ó maa ń tó bíi 70 centimetres (28 in).
Wọ́n maa ń kó ara wọn jẹ̀ lọ́pọ̀ tuutu súmọ̀ ìsàlẹ̀ òkun, wọ́n maa ń jẹ plankton, krill, amphipods, cephalopods, chaetognaths kékeré, àti ctenophores.
Wọ́n maa ń pa wọ́n fún títa tí wọ́n sì maa ń ṣètò wọn fún jílẹ.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- Froese, Rainer, and Daniel Pauly, eds. (2012). "Argentinidae" in FishBase. February 2012 version.