High Court of Lagos State
High Court of Lagos State jẹ́ ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó ní ẹ̀ka méjì, ìkan wà ní Erékùṣù Èkó tí èkejì sì wà ní Ikeja.[1][2] Olóyè olóògbé Conrad Idowu Taylor ní ó kọ́kọ́ jẹ́ adájọ́ àgbà ní High Court Of Lagos State ní ọdún 1967, kí ó tó fẹ̀yìntì.[3][4][5][6]
High Court of Lagos State | |
---|---|
Ọ̀nà àbáwọ́lé sí High Court of Lagos State | |
Established | 1964 |
Country | Nàìjíríà |
Composition method | Gómìnàn ní ó maa ń yàn wọ́n sípò |
Authorized by | Òfin ìlú Èkó |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Ernest Uwazie (26 June 2014). Alternative Dispute Resolution and Peace-building in Africa. Cambridge Scholars Publishing. pp. 44–. ISBN 978-1-4438-6254-7. http://books.google.com/books?id=MdMxBwAAQBAJ&pg=PA44.
- ↑ Shahid M. Shahidullah (19 September 2012). Comparative Criminal Justice Systems. Jones & Bartlett Publishers. pp. 348–. ISBN 978-1-4496-0425-7. http://books.google.com/books?id=eZD-MHVMHsQC&pg=PA348.
- ↑ Nigeria The Case for Peaceful and Friendly Dissolution. The Futility of the Land Use. pp. 23–. GGKEY:PB42E7G413Q. http://books.google.com/books?id=5hDJvxt_O-MC&pg=PT23.
- ↑ "The Audacity of Purpose, Articles - THISDAY LIVE". thisdaylive.com. Archived from the original on 1 July 2015. Retrieved 24 April 2015.
- ↑ Ajiroba Yemi Kotun. "Paving The Way". TheNigerianVoice. Retrieved 24 April 2015.
- ↑ "Learn About Lagos State, Nigeria - People, Local Government and Business Opportunities in Lagos". Overview of Nigeria -NgEX. Archived from the original on 3 November 2021. Retrieved 24 April 2015.