Hillary Rodham Clinton
Olóṣèlú
Hillary Diane Rodham Clinton (pípè /ˈhɪləri daɪˈæn ˈrɒdəm ˈklɪntən/; ojoibi October 26, 1947) je oloselu ara orile-ede Amerika. Lowolowo ohun ni Alakoso Oro Okere orile-ede Amerika 67th labe ijoba Aare Barack Obama. O ti je tele bi Alagba Ile Igbimo Asofin Amerika fun Ipinle New York lati 2001 de 2009. Gege bi iyawo Aare Bill Clinton, ohun lo je Iyaafin Akoko Amerika lati 1993 de 2001. Ninu idiboyan 2008, Clinton je eniagbewo fun idaloruko ipo aare egbe oloselu Democratiki.
Hillary Rodham Clinton | |
---|---|
67th United States Secretary of State | |
In office January 21, 2009 – February 1, 2013 | |
Ààrẹ | Barack Obama |
Deputy | Jim Steinberg Jacob Lew |
Asíwájú | Condoleezza Rice |
Arọ́pò | John Kerry |
United States Senator from New York | |
In office January 3, 2001 – January 21, 2009 | |
Asíwájú | Daniel Patrick Moynihan |
Arọ́pò | Kirsten Gillibrand |
First Lady of the United States | |
In office January 20, 1993 – January 20, 2001 | |
Ààrẹ | Bill Clinton |
Asíwájú | Barbara Bush |
Arọ́pò | Laura Bush |
First Lady of Arkansas | |
In office January 11, 1983 – December 12, 1992 | |
Gómìnà | Bill Clinton |
Asíwájú | Gay Daniels White |
Arọ́pò | Betty Tucker |
In office January 9, 1979 – January 19, 1981 | |
Gómìnà | Bill Clinton |
Asíwájú | Barbara Pryor |
Arọ́pò | Gay Daniels White |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kẹ̀wá 1947 Chicago, United States |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Bill Clinton |
Àwọn ọmọ | Chelsea |
Residence | Chappaqua, United States |
Alma mater | Wellesley College Yale Law School |
Profession | Lawyer |
Signature | |
Website | Official website |
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Hillary Rodham Clinton |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |