Himbasha

Búrẹ́dì ìbílè ní Ethiopia àti Eritrea

Himbasha[1] tàbí Ambasha, jẹ́ búrẹ́dì tó dùn tí wọ́n máa ń lò fún ayẹyẹ ní ilẹ̀ Ethiopia àti Eritrea.[2][3] Ó gbajúmọ̀ láàárín àwọn oúnjẹ ilè Eritea, tí wọ́n sì máa ń jẹ lásìkò ayẹyẹ. Oríṣiríṣi èròjà ni wọ́n máa ń lò láti fi se oúnjẹ yìí, ó sì ní ṣe pèlú agbègbè tàbí àdúgbò náà.

Himbasha
TypeSweet bread
Place of originEritrea, Ethiopia
Region or stateEritrean highlands, Amhara, Tigray
Main ingredientsCardamom seeds, candied ginger, raisins
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Wọ́n máa ń dára sí ara dough náà kí wọ́n tó gbé síná. Àrà tí wọ́n dá sí ara rè yìí máa ń yàtọ̀ nígbà mìíràn, àmọ́ ó jọ wíìlì.

Àfikún àwọn èròjà tí wọ́n máa ń fi si ni ọsàn, ata ilẹ̀, kóró cardamom.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Debrawork Abate (1995) (in am). የባህላዌ መግቦች አዘገጃጀት (2nd ed.). Addis Ababa: Mega Asatame Derjet (Mega Publisher Enterprise). pp. 195–196. 
  2. Warren, Olivia (2000). Taste of Tigray : Recipes from One of East Africa's Most Interesting Little Countries. Hippocrene Books, Inc.. ISBN 978-0-7818-0764-7. https://archive.org/details/tasteoferitreare00warr. 
  3. Kloman, Harry (2010-10-04). Mesob Across America: Ethiopian Food in the U.S.A. ISBN 9781450258678. https://books.google.com/books?id=4E1IlQKYeXkC&q=ga%27at&pg=PT35.