Hiram Rhodes Revels
Olóṣèlú
Hiram Rhodes Revels (September 27, 1827[1] – January 16, 1901) je omo Afrika Amerika akoko mi Ile Alagba U.S. Nitoripe o siwaju gbogbo awon omo Afrika Amerika ni Ile Asoju, ohun ni omo Afrika Amerika akoko ni Kongresi U.S bakanna. O soju fun Mississippi ni 1870 ati 1871 nigba Itunko. Titi to fi di 2011, Revels je ikan ninu awon omo Afrika Amerika mefa pere ti won ti diboyan si Ile Alagba Amerika.
Hiram Rhodes Revels | |
---|---|
United States Senator from Mississippi | |
In office February 23, 1870 – March 3, 1871 | |
Asíwájú | Albert G. Brown |
Arọ́pò | James L. Alcorn |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | [1] Fayetteville, North Carolina, U.S. | Oṣù Kẹ̀sán 27, 1827
Aláìsí | January 16, 1901 Aberdeen, Mississippi, U.S. | (ọmọ ọdún 73)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Republican (before 1874), Democratic (1874 on) [2] |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Phoebe A. Bass Revels |
Alma mater | Knox College |
Profession | Politician, Barber, Minister, College President |
Military service | |
Branch/service | Union Army |
Years of service | 1863 - 1865 |
Unit | Chaplain Corps |
Battles/wars | American Civil War |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |