Hispaniola (lati ede Hispani, La Española) je erekusu ninla ni Karibeani, to damupo Haiti ati Dominiki Olominira.

Hispaniola
Native name: La Española
View of Haitian Landscape hispaniola.jpg
View from Hispaniola
Jẹ́ọ́gráfì
Ibùdó Caribbean Sea
Àgbájọ erékùṣù Greater Antilles
Àwọn erékùṣù pàtàki Île de la Gonâve, Tortuga, Île à Vache, Isla Saona
Ààlà 76,480 km2 (29,529 sq mi)
Ipò ààlà 22nd
Etíodò 3,059 km (1,901 mi)
Ibí tógajùlọ 3,098 m (10,164 ft)
Orí ilẹ̀ tógajùlọ̀ Pico Duarte
Orílẹ̀-èdè
Hàítì Haiti
Ìlú tótóbijùlọ Port-au-Prince
Orílẹ̀òmìnira Dómíníkì Dominican Republic
Ìlú tótóbijùlọ Santo Domingo
Demographics
Ìkún 18,466,497 (as of 2005 est.)
Ìsúnmọ́ra ìkún 241.5