Hiwot Ayalew
Hiwot Ayalew Yimer ni a bini ọjọ kẹfa, óṣu March, ọdun 1990 jẹ akọṣẹmọṣẹ elere sisa ti ọna jinjin to da lori steeplechase ti metres ẹgbẹrun mẹta ti órilẹ ede Ethiopia[1]. Hiwot ṣoju fun órilẹ ede Ethiopia ninu ayẹyẹ ti olympics summer ti ọdun 2012 nibi to ti pari pẹlu ipo karun.
Hiwot at the 2015 IAAF Diamond League meeting in Doha | ||||||||||||||||
Òrọ̀ ẹni | ||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kẹta 1990 | |||||||||||||||
Height | 1.73 m (5 ft 8 in) | |||||||||||||||
Weight | 53kg | |||||||||||||||
Sport | ||||||||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia | |||||||||||||||
Erẹ́ìdárayá | Track and field | |||||||||||||||
Event(s) | 3000 metres steeplechase | |||||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Àṣèyọri
àtúnṣeHiwot gbe ipo kẹta ninu idije ilẹ Ethiopia lori metres ẹgbẹrun mẹta. Ni ọdun 2011, Hiwot yege ninu ere ti idije ile ifowo pamọsi ti commercial nibi to ti gbe ipo keji ni Jen Meda Cross Country[2]. Ni ọdun 2011, Hiwot kopa ninu ere awọn óbinrin ti idije IAAF agbaye cross country. Ni ere Bislett, Hiwot gbe ipo keje pẹlu íṣẹju aya 14:49.3 fun ẹgbẹrun marun metres. Ni ọdun 2011, Hiwot kopa ninu ere gbogbo ilẹ Afirica nibi to ti ami ẹyẹ ọla ti silver ninu steeplechase. Ni ọdun 2013, Hiwot kopa ninu idije agbaye nibi to ti pari pẹlu ipo kẹrin[3]. Ni ọdun 2014, Hiwot yege ninu idije ilẹ Afirica ni metres ẹgbẹrun mẹta[4]. Ni ọdun 2015, Hiwot kopa ninu idije agbaye to si pari pẹlu ipo kẹfa ni ilu Beijing[3].