How to Steal a Country (tiata bi Att stjäla ett land ), jẹ́ eré oníse tí ó jẹ mọ́ itan-akọọlẹ South Africa ti ọdún 2019 tí Rehad Desai ṣe olùdarí. òhun pẹ̀lú Anita Khanna àti Zivia Desai Keiper jọ sàgbéjáde rẹ̀. eré oníse náà rọ̀gbà yí títú aṣírí ìwà ìbàjẹ́ tí wọ́n fi ẹ̀sùn rẹ̀ kan Ààrẹ tẹ́lẹ̀rí Jacob Zuma àti ìdílé Gupta tí àwọn akọ̀ròyìn tó ń ṣèwádìí fi hàn.

How to Steal a Country
AdaríRehad Desai
Mark J. Kaplan
Olùgbékalẹ̀Rehad Desai
Anita Khanna
Zivia Desai Keiper
Òǹkọ̀wéAnita Khanna
OrinJannous Aukema
Ìyàwòrán sinimáNic Hofmeyr
Duncan Tilley
Shavez Ahmed
Fred Burns
Derek Allen
Ian Ross
Sandile Sethi
Eran Tahor
OlóòtúMegan Gill
Geert Veuskens
Nikki Comninos
Ilé-iṣẹ́ fíìmùUhuru Productions
OlùpínParallel 40 - Planeta Med (2021) (Spain) (all media)
Yleisradio (YLE) (2020) (Finland) (TV)
Déètì àgbéjáde
  • 26 Oṣù Kọkànlá 2019 (2019-11-26)
(Netherlands)
ÀkókòÌsẹ́jú Mọ́kàndínlọ́gọ̀rún
Orílẹ̀-èdèSouth Africa
ÈdèÈde Gẹ̀ẹ́sì

Eré oníse náà ṣe àfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù kọkànlá ọdún 2019 ni orílẹ̀ edè Netherlands. Eré oníse náà gba àdàpọ̀ àgbéyèwò láti ọwọ́ àwọn alárìíwísí.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe