Yunifásítì Howard

(Àtúnjúwe láti Howard University)

Yunifásítì Howard (ní èdè Gẹ̀ẹ́sì: Howard University tàbí Howard tàbí HU) ni yunifásítì aládáni, tó ní ìwé áṣẹ látọwọ́ ìjọba àpapọ̀ tó bùdó sí Washington, D.C. ní Amẹ́ríkà. Yunifásítì Howard jẹ́ ìkan nínú àwọn yunifásítì tí wọ́n dásílẹ̀ fún àwọn aláwọ̀dúdú (HBCU) ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Wọ́n dá Yunifásítì Howard sílẹ̀ ní 1867.

Howard University
[[File:
Ilé ìkàwé Yunifásítì Howard
|frameless|alt=]]
MottoVeritas et Utilitas
Motto in English"Truth and Service"
EstablishedOṣù Kẹta 2, 1867 (1867-03-02)
TypePrivate, HBCU
Endowment$692.8 million (2019)[1]
PresidentWayne A. I. Frederick
ProvostAnthony Wutoh[2]
Students9,399 (Fall 2019)[3]
Undergraduates6,526 (Fall 2019)[3]
Postgraduates2,873 Fall 2019)[3]
LocationWashington, D.C., United States
CampusUrban; 300 acres (1.2 km2)
Former namesHoward Normal and Theological School for the Education of Teachers and Preachers
NewspaperThe Hilltop
ColorsBlue, White, and Red[4]
              
Websitehoward.edu
Howard University logo.svg

Ìtọ́kasí

àtúnṣe