Hubert Ogunde
Òṣéré orí ìtàgé
Hubert Adédèjí Ògúnǹdé (31 May, a bi ni odun 1916 o ku ni 4 April, 1990). Hubert Adédèjì Ògúnǹdé jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ati sinnimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá láti orílẹ̀ èdè [[Naijiria]. Ó tún jẹ́ Olùkọ̀tàn, olùdarí eré orí-ìtàgé, akọrin, Òun ni olùdásílẹ̀ Ẹgbẹ́ Òṣèré Ògúnǹdé kalẹ̀, èyí tí ó jẹ́ alákọ̀ọ́kọ́ irú rẹ̀ nílẹ̀ Yorùbá àti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lálapọ̀. láì-fọ̀tá-pè, òun ni gbogbo tẹrí-tọ lè júwe gẹ́gẹ́ bí Olùdásílẹ̀ Eré Orí-Ìtàgé nilẹ̀ Nàìjíríà, tàbí ẹni tó mú ọ̀làjú wọ eré orí-ìtàgé ní Nàìjíríà.
Hubert Ogunde | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ososa, Ìpínlẹ̀ Kwara, Nigeria | Oṣù Kàrún 31, 1916
Aláìsí | April 4, 1990 Cromwell Hospital, ilesha, England | (ọmọ ọdún 73)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Investor Playwright Actor Theatre director Musician |